Book
kinihun igboro
By M.S Babatunde
   

About this book


Iru ipo wo ni a le gbe ọrẹ si ninu ọkan ẹni? Bawo ni eniyan tiṣe le fẹran ẹnikeji rẹ to ti a fi le wipe o ti ṣe aṣeju? Kini o le ja eniyan wa’lẹ lati ipo eniyan di ẹranko? Kini o le gbe ẹhọnna s’oke l’ati ipo ẹranko si ipo eniyan? Kinihun-Igboro da l’ori ọpọlọpọ akori ti nko le ṣalaye tan, o da l’ori ọrẹ, agbara, atunbi, idan, egun, ayipada-ilu, ẹgbẹ-okunkun, ẹbọra, ati-bẹẹ-bẹẹ-lọ. Kinihun-Igboro le tun mu wa ṣe iranti onkọwe pataki ilẹ Yoruba ti o ti d’oloogbe, Ọgbẹni D.O Fagunwa. O pẹ ti awọn eniyan ti nṣe ibeere fun iwe D.O Fagunwa nitori Ọgbẹni D.O Fagunwa ko kọ ju iwe marun lọ ki wọn o to ṣaisi, bata ti Baba bọ silẹ tobi gidi, amọ bi eniyan ba ka Kinihun-Igboro, a fẹrẹ fi Kinihun-Igboro ṣe ọmọ awọn iwe D.O Fagunwa ti a njẹ iran ẹ. Ẹ ka a, ki ẹ si kọ erongba yin silẹ What position can we place a friend in our heart? To what extent can a man love his brethren that we could deem it “Too much”? What can degrade a man to the level of a beast? What can upgrade a beast to the category of men? Kinihun-Igboro centered on a lot of topics that I can’t expatiate all here, topics like friendship, power, re-incarnation, magic, curse, evolution, cultism, daemons amongst more. For anyone who had read D.O Fagunwa’s novel could regard Kinihun-Igboro as its little child. Read & review. Ire o Noticed an error in this book? Send a mail to flag@okadabooks.com to report it

Please login or create an account to leave a review